Àìsáyà 22:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ògo ìdílée rẹ̀ ni yóò rọ̀ mọ́ ọn ní ọrùn: ìran rẹ̀ àti àrọ́mọdọ́mọ rẹ̀ gbogbo ohun èlò aláìlágbára láti orí abọ́ rẹ̀ dé orí ìdẹ̀ rẹ̀.

Àìsáyà 22

Àìsáyà 22:21-25