Àìsáyà 22:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, àní Olúwa àwọn ọmọ-ogun,pè ọ́ ní ọjọ́ náàláti ṣunkún kí o sì pohùnréré,kí o tu irun rẹ dànù kí o sìda aṣọ ọ̀fọ̀ bora.

Àìsáyà 22

Àìsáyà 22:8-22