Àìsáyà 21:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, ọkùnrin kan ni ó ń bọ̀wá yìínínú kẹ̀kẹ́ ogunàti àkójọpọ̀ àwọn ẹṣin.Ó sì mú ìdáhùn padà wá:‘Bábílónì ti ṣubú, ó ti ṣubú!Gbogbo àwọn ère òrìṣàa rẹ̀ló fọ́nká lórí ilẹ̀!’”

Àìsáyà 21

Àìsáyà 21:3-16