Àìsáyà 21:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni alóre náà kígbe,“Láti ọjọ́ dé ọjọ́, Olúwa mi, mo dúró ní ilé ìṣọ́,alaalẹ́ ni mo fi ń wà nípò mi.

Àìsáyà 21

Àìsáyà 21:2-9