Àìsáyà 21:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn mí dàrú,ẹ̀rù mú jìnnìjìnnì bá mi,tanmọóko tí mo ti ń fẹ́ ẹ́ ríti wá di ìpayà fún mi.

Àìsáyà 21

Àìsáyà 21:1-7