Àìsáyà 21:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú èyí, ìrora kómi lára gírígírí,ìrora gbámimú, gẹ́gẹ́ bí i tiobìnrin tí ń rọbí,Mo ta gbọ̀n-ọ́n gbọ̀n-ọ́n nítorí ohun tí mo gbọ́,ọkàn mi pòrúúrù nípa ohun tí mo rí.

Àìsáyà 21

Àìsáyà 21:1-6