Àìsáyà 21:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ ìmọ̀ tí ó kan ihà lẹ́bàá òkun:Gẹ́gẹ́ bí ìjì líle ti í jà kọjá ní ilẹ̀ ní gúṣù,akógunjàlú kan wá láti ihà,láti ilẹ̀ ìpayà.

Àìsáyà 21

Àìsáyà 21:1-2