Àìsáyà 19:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò fi àjàkálẹ̀-àrùn kan bá Éjíbítì jà; yóò bá wọn jà yóò sì tún wò wọ́n sàn. Wọn yóò yípadà sí Olúwa, Òun yóò sì gbọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn yóò sì wò wọ́n sàn.

Àìsáyà 19

Àìsáyà 19:18-25