Àìsáyà 17:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìlú Áróérì ni a ó kọ̀ sílẹ̀fún àwọn agbo ẹran tí yóò máa sùn ṣíbẹ̀,láìsí ẹni tí yóò dẹ́rùbà wọ́n.

Àìsáyà 17

Àìsáyà 17:1-5