Àìsáyà 17:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ti gbàgbé Ọlọ́run Olùgbàlà yín;ẹ kò sì rántí àpáta náà, àní odi agbára yín.

Àìsáyà 17

Àìsáyà 17:5-12