Àìsáyà 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbohùngbohùn ń gba igbe wọn déìpẹ̀kun ilẹ̀ Móábù;ìpohùnréré wọn lọ títí dé Ẹgíláémù,igbe ẹkún wọn ni a gbọ́ títí dé kànga Élímù.

Àìsáyà 15

Àìsáyà 15:6-9