Àìsáyà 14:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe yọ̀, gbogbo ẹ̀yin Fílístínì,pé ọ̀pá tí ó lù ọ́ ti dá;láti ibi gbòngbò ejò náà ni pamọ́lẹ̀yóò ti hù jáde,èṣo rẹ̀ yóò sì jẹ́ oró ejò tíí jóni.

Àìsáyà 14

Àìsáyà 14:21-31