Àìsáyà 14:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tọ́jú ibìkan tí a ó ti pa àwọn ọmọkùnrin rẹnítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba ńláa wọn,wọn kò gbọdọ̀ dìde láti jogún ilẹ̀kí wọ́n sì bo orí ilẹ̀ pẹ̀lú àwọn ìlúu wọn.

Àìsáyà 14

Àìsáyà 14:17-30