Àìsáyà 13:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn mọ̀jèsín wọn ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́ níṣojú wọn,gbogbo ilẹ̀ wọn ni a ó kóàwọn aya wọn ni a ó sì bá dàpọ̀.

Àìsáyà 13

Àìsáyà 13:11-18