Àìsáyà 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kígbe ṣókè kí o sì kọrin fún ayọ̀, ẹ̀yin ènìyàn Ṣíhónì,nítorí títóbi ni ẹni mímọ́ kanṣoṣoti Ísírẹ́lì láàrin yín.”

Àìsáyà 12

Àìsáyà 12:3-6