Àìsáyà 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà, ìwọ yóò wí pé:“Fi ọpẹ́ fún Olúwa, ké pe orúkọ rẹ̀,Jẹ́ kí ó di mímọ̀ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè,ohun tí ó ti ṣekí o sì kéde pé a ti gbéorúkọ rẹ̀ ga.

Àìsáyà 12

Àìsáyà 12:1-6