Àìsáyà 11:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkookò yóò sì máa bá ọmọ àgùntàn gbé,àmọ̀tẹ́kùn yóò sì sùn ti ewúrẹ́ọmọ màlúù òun ọmọ kìnnìúnàti ọmọ ẹran ó wà papọ̀ọ̀dọ́mọdé yóò sì máa dà wọ́n.

Àìsáyà 11

Àìsáyà 11:1-14