Àìsáyà 11:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò sì ní inúdídùn nínú ìbẹ̀rù Olúwa.Òun kì yóò ṣe ìdájọ́ pẹ̀lú ohun tí ó fi ojúu rẹ̀ rí,tàbí pẹ̀lú ohun tí ó fi etíi rẹ̀ gbọ́,

Àìsáyà 11

Àìsáyà 11:1-7