Àìsáyà 11:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀nà gidi yóò wà fún àwọn ènìyàn an rẹ̀ tí ó ṣẹ́kùtí ó kù sílẹ̀ ní Ásíríà,gẹ́gẹ́ bí ó ti wà fún Ísírẹ́lìnígbà tí wọ́n gòkè láti Éjíbítì wá.

Àìsáyà 11

Àìsáyà 11:15-16