Àìsáyà 10:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun,yóò kán ẹ̀ka náà sọnù pẹ̀lú agbára.Àwọn igi ọlọ́lá ni a ó gé lulẹ̀Àwọn tí ó ga gogoro ni a ó rẹ̀ sílẹ̀.

Àìsáyà 10

Àìsáyà 10:26-34