Àìsáyà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àyàfi bí Olúwa àwọn ọmọ-ogunbá sẹ́ díẹ̀ kù fún wà,a ò bá ti rí bí Sódómù,a ò bá sì ti dàbí Gòmórà.

Àìsáyà 1

Àìsáyà 1:2-17