Àìsáyà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti àtẹ́lẹṣẹ̀ yín dé àtàrí yínkò sí àlàáfíà rárá,àyàfi ọgbẹ́ òun ìfarapaàti ojú egbò,tí a kò nùnù tàbí kí á dì tàbí kí a kùn ún ní òróró.

Àìsáyà 1

Àìsáyà 1:1-10