Àìsáyà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má mú ọrẹ aṣán wá mọ́!Ìríra ni tùràrí yín jásí fún mi,oṣù tuntun, ọjọ́ ọ̀sẹ̀ àti àwọn àpèjọÈmi kò lè faradà àpèjọ ibi yín wọ̀nyí.

Àìsáyà 1

Àìsáyà 1:10-17