2 Tímótíù 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìsinsinyìí lọ a fi adé òdodo lélẹ̀ fún mi, tí Olúwa onídàjọ́ òdodo, yóò fífún mi ni ọjọ́ náà kì í sì í ṣe kìkì èmi nìkan ṣùgbọ́n pẹ̀lú fún gbogbo àwọn tí ó ti fẹ́ ìfarahàn rẹ̀.

2 Tímótíù 4

2 Tímótíù 4:6-14