2 Tímótíù 4:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sa ipá rẹ láti tètè wá ṣáájú ìgbà òtútù. Éúbúlù kí ọ, àti Páúdánì, àti Línù, Kíláúdíà, àti gbogbo àwọn ará-kùnrin.

2 Tímótíù 4

2 Tímótíù 4:15-22