2 Tímótíù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nitori àwọn ènìyàn yóò jẹ́ olùfẹ́ ti ara wọn, olùfẹ́ owó, afọ́nnu, agbéraga, asọ̀rọ̀-búburú, aṣàìgbọ́ràn sí òbí, aláìlọ́pẹ́, aláìmọ́.

2 Tímótíù 3

2 Tímótíù 3:1-12