2 Tímótíù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe alábàápín pẹ̀lú mi nínú ìpọ́njú, bí ọmọ-ogun rere Jésù Kírísítì.

2 Tímótíù 2

2 Tímótíù 2:2-12