2 Tímótíù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ẹni ti ó gbà wá là, ti ó si pè wá sínú ìwà-mímọ́—kì í ṣe nípa iṣẹ́ tí a ṣe ṣùgbọ́n nípaṣẹ̀ ète àti oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀. Oore-ọ̀fẹ́ yìí ni a fi fún wa láti ìpìlẹ̀ ayérayé,

2 Tímótíù 1

2 Tímótíù 1:4-15