2 Tímótíù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run, ẹni tí èmi ń sìn pẹ̀lú ẹ̀rí-ọkàn funfun gẹ́gẹ́ bí àwọn baba mi ti í ṣe, pé ni àìsinmi lọ́sàn-án àti lóru ni mo ń ṣe ìrántí rẹ nínú àdúrà mi.

2 Tímótíù 1

2 Tímótíù 1:1-7