2 Tẹsalóníkà 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa ń ṣe nǹkan wọ̀nyí, kì í ṣe nítorí pé àwa kò ní ẹ̀tọ́ láti bèrè fún un, ṣùgbọ́n àwa ń fi ara wa ṣe àpẹẹrẹ tí ẹ ó tẹ̀lé.

2 Tẹsalóníkà 3

2 Tẹsalóníkà 3:1-17