2 Tẹsalóníkà 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A gbọ́ pé àwọn kan wà láàrin yín tí wọn jẹ́ ìmẹ́lẹ́. Wọ́n jẹ́ ìmẹ́lẹ́. Wọ́n jẹ́ atọjúlé-kiri.

2 Tẹsalóníkà 3

2 Tẹsalóníkà 3:10-18