2 Tẹsalóníkà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó yẹ kí a máa dúpẹ́ nígbà gbogbo nítorí yín, ará, àní gẹ́gẹ́ bí ó ti yẹ, nítorí pé ìgbàgbọ́ yín ń dàgbà gidigidi, àti ìfẹ́ olúkúlùkù yín gbogbo sí ara yín ń di púpọ̀.

2 Tẹsalóníkà 1

2 Tẹsalóníkà 1:1-6