2 Sámúẹ́lì 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì tẹríba, ó sì wí pé, “Kí ni ìránṣẹ́ rẹ jásí, tí ìwọ ó fi máa wo òkú ajá bí èmi.”

2 Sámúẹ́lì 9

2 Sámúẹ́lì 9:2-13