2 Sámúẹ́lì 9:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Méfibóṣétì ọmọ Jónátaanì ọmọ Ṣọ́ọ̀lù sì tọ Dáfídì wá, ó sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀, ó sì bú ọlá fún un.Dáfídì sì wí pé, “Méfibóṣétì!”Òun sì dáhún wí pé, “Wò ó, ìránṣẹ́ rẹ!”

2 Sámúẹ́lì 9

2 Sámúẹ́lì 9:1-11