2 Sámúẹ́lì 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì béèrè pé, ọ̀kan nínú àwọn ẹni tí ń ṣe ìdílé Ṣọ́ọ̀lù kù síbẹ̀ bí? Kí èmi lè ṣe oore fún un nítorí Jónátanì.

2 Sámúẹ́lì 9

2 Sámúẹ́lì 9:1-10