2 Sámúẹ́lì 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì gba àṣà wúrà tí ó wà lára àwọn ìránṣẹ Hadadésérì, ó sì kó wọn wá sí Jérúsálẹ́mù.

2 Sámúẹ́lì 8

2 Sámúẹ́lì 8:5-15