2 Sámúẹ́lì 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe, lẹ́yìn èyí, Dáfídì sì kọlu àwọn Fílístínì, ó sì tẹrí wọn ba: Dáfídì sì gba Metegamímà lọ́wọ́ àwọn Fílístínì.

2 Sámúẹ́lì 8

2 Sámúẹ́lì 8:1-10