2 Sámúẹ́lì 7:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí ìwọ ń lọ, èmi sáà gé gbogbo àwọn ọ̀ta rẹ kúrò níwájú rẹ, èmi sì ti sọ orúkọ rẹ di ńlá, gẹ́gẹ́ bí orúkọ àwọn ènìyàn ńlá tí ó wà ní ayé.

2 Sámúẹ́lì 7

2 Sámúẹ́lì 7:1-17