2 Sámúẹ́lì 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nátanì sì wí fún ọba pé, “Lọ, kí o sì ṣe gbogbo èyí tí ó wà ní ọkàn rẹ, nítorí pé Olúwa wà pẹ̀lú rẹ.”

2 Sámúẹ́lì 7

2 Sámúẹ́lì 7:1-8