2 Sámúẹ́lì 7:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí orúkọ rẹ ó ga títí láé, pé, ‘Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni Ọlọ́run lórí Ísírẹ́lì!’ Sì jẹ́ kí a fi ìdílé Dáfídì ìránṣẹ́ rẹ múlẹ̀ níwájú rẹ.

2 Sámúẹ́lì 7

2 Sámúẹ́lì 7:16-29