2 Sámúẹ́lì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó sì fi ìdílé rẹ àti ìjọba rẹ múlẹ̀ níwájú rẹ títí láé: a ó sì fi ìdí ìtẹ́ rẹ múlẹ̀ títí láé.’ ”

2 Sámúẹ́lì 7

2 Sámúẹ́lì 7:7-21