2 Sámúẹ́lì 6:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ibínú Olúwa sì ru sí Úsà; Ọlọ́run sì pa á níbẹ̀ nítorí ìṣìṣe rẹ̀; níbẹ̀ ni ó sì kù ní ẹ̀bá àpótí-ẹ̀rí Ọlọ́run.

2 Sámúẹ́lì 6

2 Sámúẹ́lì 6:4-13