2 Sámúẹ́lì 6:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Míkálì ọmọbìnrin Ṣọ́ọ̀lù kò sì bí ọmọ, títí o fi di ọjọ́ ikú rẹ̀ nítorí tí ó sọ̀rọ̀ òdì yìí sí Dáfídì.

2 Sámúẹ́lì 6

2 Sámúẹ́lì 6:17-23