2 Sámúẹ́lì 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àpótí-ẹ̀rí Olúwa sì ti wọ ìlú Dáfídì wá; Mikali ọmọbìnrin Ṣọ́ọ̀lù sì wo láti ojú fèrèsé, ó sì rí Dáfídì ọba ń fò sòkè ó sì ń jó níwájú Olúwa; òun sì kẹ́gàn rẹ̀ ní ọkàn rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 6

2 Sámúẹ́lì 6:8-22