2 Sámúẹ́lì 6:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì fi gbogbo agbára rẹ̀ jó níwájú Olúwa; Dáfídì sì wọ éfódù ọ̀gbọ̀.

2 Sámúẹ́lì 6

2 Sámúẹ́lì 6:10-19