2 Sámúẹ́lì 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì kò sì fẹ́ mú àpótí-ẹ̀rí Olúwa sọ́dọ̀ rẹ̀ sí ìlú Dáfídì; ṣùgbọ́n Dáfídì sì mú un yà sí ilé Obedì-Édómù ará Gátì.

2 Sámúẹ́lì 6

2 Sámúẹ́lì 6:5-16