2 Sámúẹ́lì 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì jẹ́ ẹni ọgbọ̀n ọdún nígbà tí ó jọba; ó sì jọba ní ogójì ọdún.

2 Sámúẹ́lì 5

2 Sámúẹ́lì 5:2-12