2 Sámúẹ́lì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábínérì sì sọ̀rọ̀ létí Béńjámẹ́nì: Ábínérì sì lọ sọ létí Dáfídì ní Hébírónì, gbogbo èyí tí ó dára lójú Ísírẹ́lì, àti lójú gbogbo ilé Béńjámíní.

2 Sámúẹ́lì 3

2 Sámúẹ́lì 3:12-21