2 Sámúẹ́lì 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábínérì sì rán àwọn oníṣẹ́ sí Dáfídì nítorí rẹ̀ wí pé, “Ti ta ni ilẹ̀ náà ń ṣe? Bá mi ṣe àdéhùn, èmi yóò si kó gbogbo Ísírẹ́lì tọ̀ ọ́ wá.”

2 Sámúẹ́lì 3

2 Sámúẹ́lì 3:9-16