2 Sámúẹ́lì 24:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì kọjá odò Jọ́dánì, wọ́n sì pàgọ́ ní Áróérì, ní ìhà apá ọtún ìlú tí ó wà láàrin àfonífojì Gádì, àti sí ìhà Jásérì.

2 Sámúẹ́lì 24

2 Sámúẹ́lì 24:1-8